歌词
@migu music@
Ololufe - WizKid/Wande Coal
Lyrics by:Ayodeji Ibrahim Balogun/Peace Emmanuel Oredope/Olajumoke Olayiwola/Oluwatobi Ojosipe
Composed by:Ayodeji Ibrahim Balogun/Peace Emmanuel Oredope/Olajumoke Olayiwola/Oluwatobi Ojosipe
Produced by:P Priime/Olajumoke Olayiwola
I can't believe that she don't
And the thing I believe go
She say W mo cold
O wa sọpẹ W mi o cold o
P
Wanna be on your show
Wanna put me on your shoulder
Layẹmi sọfun wọn mo n'ifé mo n'ife e gan ni
Fine lady girl you different you different gan ni o
I no know why but mo miss ẹ mo miss ẹ gan ni o
Bad girl I'm addicted addicted gan ni o
Iwọ l'ololufẹ my darling
Iwọ l'ololufẹ mi mo n'ifẹ rẹ
Iwọ l'ololufẹ my darling
Iwọ l'ololufẹ mi mo n'ifẹ rẹ
Giddem
Hmm sọ fun wọn mo n'ifẹ
Mo ni Fọlashade
Sọ fun ẹ pe mo n'ifẹ mo n'ifẹ gan ni o
Layẹmi Olayẹmi mo n'ifẹ
Funkẹ sọ fun ẹ mo n'ifẹ
Titilọla hmm sọ fun ẹ mo n'ifẹ
Moni Fọlashade
Sọ fún ẹ pe mo n'ifẹ mo n'ife gan ni
Iwọ l'ololufẹ my darling
Iwọ l'ololufẹ mi mo n'ifẹ rẹ
Iwọ l'ololufẹ my darling
Iwọ l'ololufẹ mi mo n'ifẹ re
Ko ko ko ko
Konkobilo ko ko ko
Ọwá fẹ pàdé mí ní ìsàlè
Òye ká fún konkobilo
Ko ko ko ko
Owa fẹ jẹ ko ko ko ko
Moni ko pàdé mí ní ìsàlè
Ìyẹn gan lo n ṣe ko ko
Iwọ l'ololufẹ my darling
Iwọ l'ololufẹ mi mo n'ifẹ rẹ
Iwọ l'ololufẹ my darling
Iwọ l'ololufẹ mi mo n'ifẹ rẹ
Giddem
Layẹmi Olayẹmi mo n'ifẹ
Funkẹ sọ fun wọn mo n'ifẹ eh
Titilọla hmm so fun ẹ mo n'ifẹ
Mo ni Fọlashade
Sọ fún ẹ pe mo n'ifẹ n'ifẹ gan ni
Gbé mi de bẹ
Gbé mi de gbe
Gbé mi de bẹ de bẹ
Gbe
Wọn lo wa ji
Gbé mi de bẹ
Wọn ní mo ji
Won ní pe ki mo ji
Kini mo de
Ani kí ló gbé
Wọn ni ko lo wi
Mo ni mo de
Wọn ni mi o dé
Mo gbéra dídé
Mo gbéra dídé
Mo gbéra dídé
Mo gbéra dídé
Mo gbéra dídé
Mo gbéra dídé
展开